Akinyemi Tobi

Lati samisi akoko isinmi ti n bọ ni ibamu pẹlu Idasile ati Agbekale ti ZoidPay Chrome Extension, a n kede ifilọlẹ ti Ayeye “Riraja Pelu Crypto” Akoko Ni Agbaye.

Eto idakale ZoidPay ti n dagba lopolopo ni awọn oṣu sẹhin. Iwadi ti a ṣe ṣaaju ki o to bẹrẹ ifilole naa fihan wa alaafo nla laarin cryptocurrency ati lilo rẹ gangan lati ra awọn nkan.

Ni awọn ona miiran, cryptocurrency ni akọkọ, ṣee lo bi owo, ṣugbọn, o tun di ohun elo kara-kata. Kii ṣe pe o jẹ ohun buburu, o jade lati idi-le atilẹba ti Satoshi Nakamoto fun ra re: eto isanwo itanna elegbe-si-ẹlẹgbẹ.

--

--